NKAN TI SAULU O MO FUN 40 YEARS
Nkan Meji Yi Sho Ototo. Oto Ni Emi Olorun, Oto Naa Si Ni Anu Olorun.. Emi Olorun Le Fi Eniyan Si Le, Ki Anu Olorun Shi Wa Sibe Digbi Digbi Fun Onitohun.Looto Saulu Mo Wipe Emi Olorun Ti Fi Ohun Si Le, Sugbon Dafidi Mo Wipe Kii Se Emi Olorun Nikan Ni O Fi Saulu Si Le, Dafidi Mo Wipe, Olorun Mu Anu Re Kuro Lodo Saulu Pelu. Bawo Dafidi Se Mo, Ti Saulu Fun Rare Ko Se Mo ?. Oluwa So Fun Dafidi.
Wo Ese Bibeli Yi.
5 Ṣugbọn ãnu mi kì yio yipada kuro lọdọ rẹ̀, gẹgẹ bi emi ti mu u kuro lọdọ Saulu, ti emi ti mu kuro niwaju rẹ.
(2 Samuel 7 Vs 14 NKJV )
Mimo Pe Olorun Ti Mu Anu Olorun Kuro Lodo Saulu, Pelu Idi Ti Dafidi O Se Fi Owo Kan Saulu Lati Pa,Nitori Dafidi Mo Wipe Saulu Ti Di Oku Nipase Anu Olorun Ti O Kuro Lodo Re. . O Kuku Pe Dafidi, Ki O Ge Eti Aso Saulu Ju Ki O Dunbu Re Lo.
Bi Emi Olorun Ba Fi Eyan Sile, Bi Anu Olorun Ba Shi Pelu Onitoun, Onitohun Shi Le Gbadura Ki Emi Olorun Pada To Wa, Olorun Yi O Si Dahun. (Fun Apeere Samsoni). Sugbon Ti Anu Ba Ti Kuro Lodo Eniyan, Onitohun Ti Di Oku Ti O Rin Laarin Awon Eyan. .
E Wo Ohun To Sele Si Saulu Nigbati Anu Olorun Ti Kuro Lodo Re.
* Saulu Gbadura Si Olorun, Olorun Ko Dahun ( 1 Samueli 28 Vs 6)
* Saulu Ti Emi Olorun Ti Fi Si Le, Lo Sona Lodo Awon Woli Ti EMI Olorun Wa Pelu Won , Awon Woli Na, O Ri Nkankan So Nitori Olorun Ko Soro Ksnkan Fun Won. (1 Samueli 28 Vs 6)
* Ogun Beere Sini Dide Lotun Ati Losi Fun Saulu (I Samueli 28 Vs 5)
* Saulu Wa Ninu Iforo Emi Ati Ipaya Fun 40 Years Laiyi Ri Olutunu Abi Oluranlowo
* Saulu Di Aboku Soro, ( 1 Samueli 28 Vs 8)
* Akoni Saulu Si Ku Bi Adiye.( 1 Samueli 31 Vs 13).
Idajo Ati Ijeni Niya Olorun To Le Ju Ni Aiye Yi Ni, Ki Olorun Mu Anu Re Kuro Lodo Eniyan. Oku Sanju Eniti Olorun Ba Anu Re Kuro Ni Odo Re Lo. Aigboran Ojo Kansoso Lo Mu Anu Olorun Kuro Lodo Saulu Ati Idile Re. Olorun O Ni Gba Anu Re Kuro Lodo Re Ati Idile Re.
Ese Ni O Ma Jeki Olorun Mu Anu Jina Si Eniyan. E Da Owo Ese Duro. O Si Je Anfani Ti Awon Olododo Ma N Je Lowo Oluwa.
Ni Comment Section E Type " OLUWA MASE GBA ANU RE KURO LOWO MI "
Ire o

Comments
Post a Comment